BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
Wo bí ìgbẹ́jọ́ kòtẹ́milọ́rùn tí Baba Ijesha pè lórí bí wọ́n ṣe jù ú sẹ́wọ̀n ṣe lọ lónìí l'Eko
Agbẹjọro Baba Ijesha ni ''awijare wa ni pe gbogbo nnkan ti adajọ sọ ni ile ẹjọ giga ko tẹ wa lọrun.
Gbogbo ìgbà tí mo gbé ìpèníjà dé iwájú ìyàwó Ààrẹ Tinubu ló ń bá mi wá ọ̀nà àbáyọ - Gómìnà Ademola Adeleke
Agbẹnusọ Gomina Adeleke, Ọlawale Rasheed, kede pe Abilekọ Titilọla Adeleke ni obinrin akọkọ l’Ọṣun.
Ẹ̀rù ló ń ba ọ̀gá àgbà ọlọ́pàá pé ọlọ́pàá àpapọ̀ yóò di àtẹ̀mẹ́rẹ̀, ló ṣe tako ìdásílẹ̀ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ - Onímọ̀ ètò àbò
Akin Adeyi ni ti ijọba ba ṣe idasilẹ ọlọpaa ipinlẹ, o ṣeeṣe ki ẹtanu wa latari pe awọn ọlọpaa ipinlẹ naa yoo maa ṣe iṣẹ ju ọlọpaa ijọba apapọ.
Ẹ jẹ́ kí n san N200,000 owó ìtanràn ẹ̀ṣẹ̀ mi fun yín, kí n sì máa lọ sílé - Bobrisky bẹ kóòtù
Bobrisky rọ kootu pe ki wọn jẹ koun fowo naa tan ọran kikan owo naira labuku toun da lode sinima Ẹniọla Ajao, ti wọn tori rẹ mu oun.
Àwọ́n dókítà gbé oyún oṣù méje àbọ̀ jáde nínú ìyá tí àdó olóró Israel pa
Awọn dokita ni o yẹ ki ọmọ naa ṣi wa ninu ikun iya rẹ di akoko yii, amọ, ogun to n lọ lọwọ ko fun un lanfani yii.
Sọ́jà méjì jalè níléeṣẹ́ Dangote, àkàrà tú sépo, Kakí bọ́ lọ́rùn wọn
Atẹjade ti Adari ikede nileeṣẹ ologun orilẹ-ede yii, Ọgagun Onyema Nwachukwu, fi sita lọjọ Aje, ṣalaye pe ina ọba ni awọn ologun meji naa ji fa lati ibudo ifọpo Dangote.
Fídíò, "Mo fi èèpo ẹ̀gẹ́ ṣe èlùbọ́ torí ọ̀dá owó fún àwa méje láti jẹ ọkà, ẹnìkan kú, àwa mẹ́fà dèrò ilé ìwòsàn"Duration, 6,45
BBC dé ìlú Ogbomoso níbi tí ọmọ kan ti kú lásìkò tí òun àti ẹbí rẹ̀ jẹ ọkà tí wọn fi èèpo ẹ̀gẹ́ ṣe, ìyá tó ro ọkà náà àti ọkọ rẹ̀ ṣàlàyé ìdí tí wọn fi ṣe bẹ́ẹ̀.
Olùdíje sípò gómìnà mẹ́ta kọ̀wé ẹ̀sùn kòtẹ́milọ́rùn sí Abuja lórí ètò ìbò abẹ́lé APC l'Ondo
Alaga igbimọ to dari eto idibo abẹle naa nipinlẹ Ondo, Gomina ipinlẹ Kogi, Ahmed Usman Ododo lo kede Lucky Aiyedatiwa gẹgẹ bi ẹni to bori.
Àwọn orílẹ̀èdè Áfíríkà bẹ̀rẹ̀ ìpàdé àpérò láti ṣẹ́ eegun ẹ̀yìn àwọn agbésùnmọ̀mí
Ọjọ Aje oni ati ọjọ isẹgun ọla ni ipade naa yoo fi waye eyi ti awọn olori orilẹede nilẹ adulawọ yoo peju si.
Akintoye àti Igboho ń sọ tiwọn ni, àtúntò ni a dúró fún – Afenifere
Lẹta ọhun, ti wọn kọ lọjọ kẹtadinlogun, oṣu Kẹrin, ọdun 2024 yii ni Akintoye, Igboho ati Ola Ademola buwọlu.
Níbo lẹran màálú onímájèlé 50 kángun sí ní Ilorin lẹ́yìn tí ìjọba gbé ọjà ẹran Mandate tìpa?
Kọmisona feto ọgbin ni Ipinlẹ Kwara, Arabirin Thomas Adebayo ṣalaye pe, awọn ti lọ inu ọja naa lati ko awon ẹran naa.
Wo ilé ẹ̀kọ́ alákọ̀bẹ́rẹ̀ nílùú Eko tó ń gba N42m lórí ọmọ kan lọ́dún
Ọpọ ọmọ Naijiria lo ti n fi ẹhonu wọn han lori ayelujara lori owo gọbọi tawọn obi yoo maa san nile ẹkọ naa.
Ìròyìn Àkàgbádùn
Fídíò, Wo ọ̀pọ̀ àkóbá tí òfin ìjọba ń ṣe fún okòwò epo bẹntiró lẹ̀nu bodè Nàíjíríà sí ilẹ̀ BeninDuration, 4,11
Ọpọ awọn onta epo yii si lo n fi ika hanu pe inu okoowo yii ni awọn ti n bọ ara awọn ati idile awọn amọ ti gbogbo rẹ ti n doju de bayii.
Wo ìgbésẹ̀ tí Toyin Abraham gbé bí ìjà láti di ẹni àkọ́kọ́ lágbo tíátà ṣe ń wáyé láàrín àwọn òṣèré
Abraham ni asiko ti to fun awọn lati gbe ara wọn lárugẹ, ki wọn si yago fun kikorira ara wọn tabi fífi ẹgbẹkẹgbẹ ni ọna ti ko ni alaafia.
Ọkọ̀ ojú omi tó kó èèyàn 300 dojúdé ní Central African Republic, èèyàn 58 jáde láyé
Ẹnikan ti iṣẹlẹ naa ṣoju rẹ sọ fun ileeṣẹ iroyin RFI pe “iṣẹlẹ yii jẹ eyii to ba eeyan lẹru gidi.
Láti orí Fayoṣe dé Yahaya Bello, wo àwọn gómìnà tí wọ́n ti pitú fún EFCC rí
Eyi kọ lakọọko tawọn gomina yoo ti fọgbọn alumọkọrọyi japa mọ EFCC lọwọ, ti ajọ naa yoo si pada fọwọ ofin mu wọn.
Wo bí Meta ṣe fẹ́ fòpin sí gbígbà tábi fífi fọ́tò àti fídíò ìhòhò ránṣẹ́ lórí Instagram
Ileeṣẹ naa sọ pe oun maa lo imọ ijinlẹ lati mọ irufẹ atẹjiṣẹ DM to ni fọto tabi fidio ihoho.
Ilé aṣòfin Togo buwọ́lu òfin tí yóò mú kí Ààrẹ wà lórí oyè fún ọdún 26
Pẹlu ofin yii, Faure Gnassingbé yoo wa lori alefa titi di ọdun 2031.
Nǹkan tí ó le mú ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ dínkù ní Nàìjíríà rèé - Ẹgbẹ́ àgbẹ̀
Dasaolu ni loootọ ni pe ọrọ aabo lo le ọpọ agbẹ kuro loko amọ to woye pe eto aabo Naijiria ti gbopọn si ju ti tẹlẹ lọ.
Báwo ni ohun ìjà olóró Iran ṣe lágbára tó sí ti Israel?
Ajọ International Institute for Strategic Studies (IISS) ṣapejuwe agbara awọn ohun ija oloro ileeṣẹ ologun orileede mejeeji yii nipa lilo ọrọ awọn agbẹnusọ, ati awọn miran to ṣee tọka si lati fi gbe abajade wọn sita.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo da ibùba àwọn ajìjàgbara Oodua Nation wò nílùú Ibadan
Bẹẹ ba gbagbe, awọn ikọ ajijagbara Oodua Nation yii lo kọlu ọgba ọfisi gomina ipinlẹ Oyo ati ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Oyo ti wọn gbero lati gba ijọba
Israel ju àdó olóró sí àárín gbùngbùn Iran, ariwo sọ
Iran la gbọ pe wọn ti gbaradi gidi nigba ti awọn Israel sọ pe awọn yoo gbẹsan ikọlu ti awọn ara Iran ṣe si wọn lọjọ Abamẹta to kọja.
Ọ̀gá ọlọ́pàá pàṣẹ kí àwọn ẹ̀sọ́ ààbò tó wà lẹ́yin Yahaya Bello kúrò
Ọga ọlọpaa lo kede pe ki awọn ọlọpaa to n ṣọ gomina ana naa kuro lẹyin rẹ ninu atẹjade ti nọmba rẹ jẹ CB:4001/DOPS/PMF/FHQ/ABJ/VOL.48/34, eyi ti ileeṣẹ ọlọpaa gbe jade laarọ oni, ọjọ Ẹti, gẹgẹ bi iwe iroyin PUNCH ṣe kọ ọ.
Ìròyìn Pàtàkì
Kọ́milẹ́kọ̀ọ́
Móríwú
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Àwọn agbébọn kọlu baálè méjì l’Ogun, wọ́n pa ẹ̀ṣọ́ aláàbò kan
O ṣoju mi koro kan ti ko darukọ rẹ, sọ pe ori ati ejika ni ibọn ti ba awọn baalẹ naa.
Kóótù gba onídùúró Cubana Chief Priest pẹ̀lú mílíọnù mẹ́wàá náírà
Bi ẹ ko ba gbagbe, laipẹ yii ni ile-ẹjọ giga apapọ ju Bobrisky sẹwọn oṣu mẹfa gbako pẹlu iṣẹ aṣekara lai fi aye silẹ fun owo itanran rara.
Ọdún ọmọ ìlú Ìbarà bẹ̀rẹ̀ l’Abẹ́òkúta lákọ̀tun
Ẹẹkan ṣoṣo laarin ọdun mẹta ni ayẹyẹ Ọdun ọmọ Ibara maa n waye, nibi ti wọn ti maa n ṣafihan awọn ohun iṣẹmbaye wọn bii Yemọja, Ẹfẹ ati Gẹlẹdẹ, gẹgẹ bi a ṣe gbọ.
Àwọn agbébọn yawọ abúlé, jí àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ gbe ní Katsina
Iṣẹlẹ yii ti sọ ọpọ awọn to n gbe lagbegbe naa di alainile lori ati ẹru awọn ajinigbe.
Bíṣọ́ọ̀bù tí wọ́n gún lọ́bẹ lóun ti dáríji àwọn tó kọlu oun
Ileeṣẹ ọlọpaa to fidi ikọlu ọhun mulẹ fawọn akọroyin sọ pe awọn agbebọn lo ṣe ikọlu naa, ti wọn si ṣe ọpọ awọn olujọsin, to fi mọ awọn olori ijọ leṣe.
Ọ̀rọ̀ epo pupa dá wáhàlá láàrin ìyá àti ọmọ rẹ̀ l'Osun, ẹ̀mí ìyá bọ́ síi
Nigba to fi idi iṣẹlẹ naa fun BBC News Yoruba, agbenusọ ọlọpaa ipinlẹ Osun, Yemisi Opalola ni iwadii ti bẹrẹ lati mọ ohun to ṣokunfa aawọ naa.
Ilé ẹjọ́ buwọ́lu ìyọ̀nípò Ganduje, ariwo sọ
Ẹsun siṣe owo ilu mọkumọku ni wọn fikan Ganduje
A máa ṣe ìkọlù sí Iran padà – Israel fèsì
Netanyahu sọ pe awọn eeyan Isrẹli gan-an ti n dira ogun lati awọn ọdun diẹ sẹyin. Koda, ni gbogbo ọsẹ meloo sẹyin pẹlu ni wọn fojoojumọ mura silẹ de ogun ti Iran le gbe ko wọn.
Ààrẹ Bọla Tinubu kéde ọjọ́ keje, oṣù kẹrin ọdún gẹ́gẹ́ bí àyájọ́ ọjọ́ àwọn ọlọ́pàá
Igbakeji Aarẹ, Kashim Shettima to ṣoju Aarẹ Tinubu sọ pe latigba toun ti gba ijọba lọdun 2023 ni iṣakoso oun ti bẹrẹ igbesẹ lori atunto ninu iṣẹ ọlọpaa.